1Ọlọ́run ń ṣàkóso nínú ìpéjọpọ̀ ńlá,
2“Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa gbèjà àwọn aláìṣòdodo
3Gbèjà àwọn aláìlágbára àti aláìní baba;
4Gba àwọn aláìlágbára àti aláìní;
5“Wọn kò mọ̀ ohun kankan,
6“Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”;
7Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ó kú bí ènìyàn lásán;
8Dìde, Ọlọ́run, ṣe ìdájọ́ ayé,