1Nípa Ammoni.
2Ṣùgbọ́n ọjọ́ náà ń bọ̀,”
3“Hu, ìwọ Heṣboni, nítorí Ai tí rún!
4Èéṣe tí ìwọ fi ń ṣògo nínú àfonífojì rẹ,
5Èmi yóò mu ẹ̀rù wá lórí rẹ
6“Olúwa àwọn ọmọ-ogun.
7Nípa Edomu.
8Yípadà kí o sálọ, sá pamọ́ sínú ihò,
9Tí àwọn tí ń ṣa èso bá tọ̀ ọ́ wá;
10Ṣùgbọ́n èmi yóò tu Esau sí ìhòhò,
11Fi àwọn ọmọ aláìní baba sílẹ̀
12Èyí ni ohun tí Olúwa wí bí ẹnikẹ́ni tí kò bá yẹ kí ó mu ago náà bá mú un, kí ló dé tí ìwọ yóò fi lọ láìjìyà? Ìwọ kò ní lọ láìjìyà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò mú un.
13Èmi fi ara mi búra ni Olúwa wí, wí pé, “Bosra yóò ba ayé ara rẹ̀ jẹ́. Yóò di ẹni ẹ̀gàn, ẹni èpè àti ẹni ègún, àti gbogbo ìlú rẹ̀ yóò di ìbàjẹ́ títí láé.”
14Ní gbígbọ́, èmi ti gbọ́ ìró kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa,
15“Ní báyìí, èmi yóò sọ ọ́ di
16Ìpayà tí ìwọ ti fà sínú
17“Edomu yóò di ahoro
18Gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe gba Sodomu
19“Bí i kìnnìún ni òun ó gòkè wá láti igbó Jordani sí orí ilẹ̀ ọlọ́ràá,
20Nítorí náà, ẹ gbọ́ ohun tí
21Ilẹ̀ yóò mì tìtì nípa ariwo ìṣubú wọn,
22Wò ó! Ẹyẹ idì yóò gòkè fò wálẹ̀,
23Nípa Damasku.
24Damasku di aláìlera,
25Kí ló dé tí ìlú olókìkí di ohun ìkọ̀sílẹ̀;
26Lóòtítọ́, àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ yóò ṣubú lójú pópó,
27“Èmi yóò fi iná sí odi Damasku,
28Nípa ìlú Kedari àti ìjọba Hasori èyí ti Nebukadnessari ọba Babeli dojú ìjà kọ,
29Àgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọn ni wọn ó kó lọ;
30“Sálọ kíákíá!
31“Dìde kí o sì dojú ìjà kọ orílẹ̀-èdè tí ó wà nínú ìrọ̀rùn,
32Àwọn ìbákasẹ á di ẹrù
33“Hasori yóò di ibi ìdọdẹ àwọn akátá,
34Èyí ní ọ̀rọ̀ Olúwa èyí tí ó tọ Jeremiah wòlíì wá nípa Elamu ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Sedekiah ọba Juda.
35Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ:
36Èmi yóò mú kí afẹ́fẹ́ orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin
37Èmi yóò kẹ́gàn Elamu níwájú àwọn ọ̀tá wọn,
38Èmi yóò sì gbé ìtẹ́ mi kalẹ̀ ní Elamu,
39“Síbẹ̀, èmi yóò dá ìkólọ