We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Jeremiah 47

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Jeremiah 46 Jeremiah Jeremiah 48 →

1Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tó tọ wòlíì Jeremiah wá nípa àwọn Filistini, kí ó tó di pé Farao dojúkọ Gasa.

2Báyìí ni Olúwa wí:

3nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ìró títẹ̀lé pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin alágbára

4Nítorí tí ọjọ́ náà ti pé

5Gasa yóò fá irun orí rẹ̀ nínú ọ̀fọ̀.

6“Ẹ̀yin kígbe, ‘Yé è, idà Olúwa,

7Ṣùgbọ́n báwo ni yóò ṣe sinmi,

← Jeremiah 46 Jeremiah Jeremiah 48 →

Jeremiah 47 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002