We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Jeremiah 46

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Jeremiah 45 Jeremiah Jeremiah 47 →

1Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Jeremiah wòlíì wá nípa àwọn Orílẹ̀-èdè.

2Nípa Ejibiti.

3“Ẹ múra àpáta, èyí tí ó tóbi, àti èyí tí ó kéré,

4Ẹ di ẹṣin ní gàárì,

5Kí ni nǹkan tí mo tún rí?

6“Ẹni tí ó yára kì yóò le sálọ,

7“Ta ni èyí tí ó gòkè wá bí odò Ejibiti,

8Ejibiti dìde bí odò náà,

9Ẹ gòkè wá ẹ̀yin ẹṣin,

10Ṣùgbọ́n ọjọ́ náà jẹ́ ti Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,

11“Gòkè lọ sí Gileadi, kí o sì mú ìkunra,

12Àwọn orílẹ̀-èdè yóò gbọ́ nípa ìtìjú rẹ,

13Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó bá Jeremiah wòlíì nì sọ nípa wíwá Nebukadnessari ọba Babeli láti lọ dojú ìjà kọ Ejibiti:

14“Kéde èyí ní Ejibiti, sì sọ ọ́ ní Migdoli,

15Èéṣe tí àwọn akọni rẹ fi ṣubú?

16Wọn yóò máa ṣubú léraléra

17Níbẹ̀ ni wọn ó kígbe pé,

18“Bí èmi ti wà láààyè,” ni ọba,

19Ìwọ, ọmọbìnrin ti ń gbé Ejibiti

20“Ẹgbọrọ abo màlúù tó lẹ́wà ní Ejibiti

21Àwọn jagunjagun rẹ̀

22Ejibiti yóò pòṣé bí ejò tí ń sá

23Wọn o gé igbó rẹ̀ lulẹ̀,” ni Olúwa wí,

24A ó dójútì ọmọbìnrin Ejibiti,

25Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí pé: “Èmi yóò rọ̀jò ìyà mi sórí Amoni òrìṣà Tebesi, sórí Farao, sórí Ejibiti àti àwọn òrìṣà rẹ̀ àti sórí àwọn ọba rẹ̀ àti sórí àwọn tó gbẹ́kẹ̀lé Farao.

26Èmi ó sì fi wọ́n lé àwọn tó wá ẹ̀mí wọn lọ́wọ́, lé Nebukadnessari ọba Babeli, ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, Ejibiti yóò sì di gbígbé bí i ti àtijọ́,” ni Olúwa wí.

27“Má bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu ìránṣẹ́ mi,

28Má bẹ̀rù, Jakọbu ìránṣẹ́ mi,

← Jeremiah 45 Jeremiah Jeremiah 47 →

Jeremiah 46 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002