1“Tẹ́tí sí èyí, ìwọ ilé e Jakọbu,
2ìwọ tí ò ń pe ara rẹ ní ọmọ ìlú mímọ́ n nì
3Èmi sọ àsọtẹ́lẹ̀ àwọn nǹkan ti tẹ́lẹ̀ lọ́jọ́ tó ti pẹ́,
4Nítorí mo mọ bí ẹ ti jẹ́ olórí kunkun tó;
5Nítorí náà mo ti sọ nǹkan wọ̀nyí fún ọ
6Ìwọ ti gbọ́ àwọn nǹkan wọ̀nyí; wo gbogbo wọn.
7A dá wọn ní àkókò yìí kì í ṣe láti ìgbà pípẹ́
8Ìwọ a ha ti gbọ́ tàbí ó ti yé ọ bí
9Nítorí orúkọ ara mi, mo dáwọ́ ìbínú mi dúró;
10Wò ó, èmi ti tún ọ ṣe, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé
11Nítorí orúkọ mi, nítorí orúkọ mi, mo ṣe èyí.
12“Tẹ́tí sí mi, ìwọ Jakọbu
13Ọwọ́ mi pàápàá ni ó fi àwọn ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,
14“Gbogbo yín, ẹ péjọ kí ẹ sì gbọ́.
15Èmi, àní Èmi ló ti sọ̀rọ̀;
16“Ẹ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi kí ẹ sì dẹtí sí èyí:
17Èyí ni ohun tí Olúwa wí,
18Bí ó bá ṣe pé ìwọ bá ti tẹ́tí sílẹ̀ sí àṣẹ mi,
19Àwọn ọmọ rẹ ìbá ti dàbí iyanrìn,
20Fi Babeli sílẹ̀,
21Òrùngbẹ kò gbẹ wọ́n nígbà tí ó kó wọn
22“Kò sí àlàáfíà,” ni Olúwa wí,