1Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin erékùṣù:
2Ó ṣe ẹnu mi bí idà tí a pọ́n,
3Ó sọ fún mi pé, “Ìránṣẹ́ mi ni ìwọ í ṣe,
4Ṣùgbọ́n èmi sọ pé, “Mo ti ṣe wàhálà lórí asán;
5Nísinsin yìí Olúwa wí pé
6Òun wí pé:
7Ohun tí Olúwa wí nìyìí,
8Ohun tí Olúwa wí nìyìí:
9láti sọ fún àwọn ìgbèkùn pé, ‘Ẹ jáde wá,’
10Ebi kì yóò pa wọ́n bẹ́ẹ̀ ni òǹgbẹ kì yóò gbẹ wọ́n,
11Èmi yóò sọ gbogbo àwọn òkè ńlá mi di ojú ọ̀nà
12Kíyèsi i, wọn yóò wá láti ọ̀nà jíjìn
13Ẹ hó fún ayọ̀, ẹyin ọ̀run;
14Ṣùgbọ́n Sioni sọ pé, “Olúwa ti kọ̀ mí sílẹ̀,
15“Ǹjẹ́ abiyamọ ha le gbàgbé ọmọ ọmú rẹ̀
16Kíyèsi i, mo ti kọ ọ́ sí àtẹ́lẹwọ́ mi
17Àwọn ọmọ rẹ ti kánjú padà,
18Gbójú rẹ sókè kí o sì wò yíká;
19“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a tí run ọ́, a sì sọ ọ́ di ahoro
20Àwọn ọmọ tí a bí ní àkókò ọ̀fọ̀ rẹ
21Nígbà náà ni ìwọ yóò sọ ní ọkàn rẹ pé,
22Ohun tí Olúwa Olódùmarè wí nìyìí,
23Àwọn ọba ni yóò jẹ́ alágbàtọ́ baba fún ọ,
24Ǹjẹ́ a le gba ìkógun lọ́wọ́ jagunjagun,
25Ṣùgbọ́n ohun tí Olúwa wí nìyìí:
26Èmi yóò mú kí àwọn aninilára rẹ̀ jẹ ẹran-ara wọn;