We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 47

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 46 Isaiah Isaiah 48 →

1“Sọ̀kalẹ̀, jókòó nínú eruku,

2Mú òkúta-ọlọ kí o sì lọ ìyẹ̀fun;

3Ìhòhò rẹ ni a ó sí síta

4Olùràpadà wa Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀

5“Jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, lọ sínú òkùnkùn,

6Inú bí mi sí àwọn ènìyàn mi

7Ìwọ wí pé, ‘Èmi yóò tẹ̀síwájú títí láé—

8“Nísinsin yìí, tẹ́tí sílẹ̀, ìwọ oníwọ̀ra ẹ̀dá

9Méjèèjì yìí ni yóò wá sórí rẹ

10Ìwọ ti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ìwà ìkà rẹ

11Ìparun yóò dé bá ọ

12“Tẹ̀síwájú nígbà náà, pẹ̀lú àfọ̀ṣẹ rẹ

13Gbogbo ìmọ̀ràn tí o ti gbà ni

14Lóòótọ́ wọ́n dàbí ìṣẹ́pẹ́ igi;

15Gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe fún ọ nìyìí

← Isaiah 46 Isaiah Isaiah 48 →

Isaiah 47 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002