1Kíyèsi i, Olúwa yóò sọ ohun
2bákan náà ni yóò sì rí
3Ilé ayé ni a ó sọ di ahoro pátápátá
4Ilẹ̀ ayé ti gbẹ ó sì sá,
5àwọn ènìyàn ayé ti bà á jẹ́;
6Nítorí náà, ègún kan ti jẹ ayé run;
7Wáìnì tuntun ti gbẹ, àjàrà sì ti rọ,
8Àríyá ti ṣaworo ti dákẹ́
9Kò ṣe é ṣe fún wọn láti máa mu wáìnì pẹ̀lú orin kíkọ mọ́
10Ìlú tí a run ti dahoro,
11Ní òpópónà ni wọ́n ti ń kígbe fún wáìnì
12Ìlú ni a ti fi sílẹ̀ ní ahoro,
13Bẹ́ẹ̀ ni yóò sì rí ní orí ilẹ̀ ayé
14Wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì hó fún ayọ̀;
15Nítorí náà ní ìlà-oòrùn ẹ fi ògo fún Olúwa;
16Láti òpin ayé wá ni a ti gbọ́ orin;
17Ìpayà, isà òkú, àti ìdẹ̀kùn ń dúró dè ọ́,
18Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá nítorí ariwo ìpayà
19Ilẹ̀ ayé ti fọ́
20Ilẹ̀ ayé yí gbiri bí ọ̀mùtí,
21Ní ọjọ́ náà ni Olúwa yóò jẹ ẹ́ ní yà
22A ó sì kó wọn jọ pọ̀,
23A ó rẹ òṣùpá sílẹ̀, ojú yóò sì ti oòrùn;