We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 23

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 22 Isaiah Isaiah 24 →

1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Tire.

2Dákẹ́ jẹ́ẹ́, ẹ̀yin ènìyàn erékùṣù

3Láti orí àwọn omi ńlá

4Kí ojú kí ó tì ọ́, ìwọ Sidoni àti ìwọ

5Nígbà tí ọ̀rọ̀ bá dé Ejibiti,

6Kọjá wá sí Tarṣiṣi;

7Ǹjẹ́ èyí náà ni ìlú àríyá yín,

8Ta ló gbèrò èyí sí Tire,

9Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti ṣètò rẹ̀,

10Tu ilẹ̀ rẹ gẹ́gẹ́ bí i ti ipadò odò Ejibiti,

11Olúwa ti na ọwọ́ rẹ̀ jáde sí orí Òkun

12Ó wí pé, “Kò sí àríyá fún ọ mọ́,

13Bojú wo ilẹ̀ àwọn ará Babeli,

14Hu, ìwọ ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi;

15Ní àkókò náà a ó gbàgbé Tire fún àádọ́rin ọdún, ọjọ́ ayé ọba kan. Ṣùgbọ́n ní òpin àádọ́rin ọdún wọ̀nyí, yóò ṣẹlẹ̀ sí Tire gẹ́gẹ́ bí orin àgbèrè:

16“Mú dùùrù kan, rìn kọjá láàrín ìlú,

17Ní òpin àádọ́rin ọdún náà, Olúwa yóò bá Tire jà. Òun yóò sì padà sí àyálò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí panṣágà, yóò sì máa ṣe òwò rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ ọba tí ó wà ní ilẹ̀ ayé.

18Síbẹ̀síbẹ̀ èrè rẹ̀ àti owó iṣẹ́ rẹ̀ ni a ó yà sọ́tọ̀ fún Olúwa; a kò ní kó wọn pamọ́ tàbí kí a há wọn mọ́wọ́. Ère rẹ̀ ni a ó fi fún àwọn tí ó ń gbé níwájú Olúwa, fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ àti aṣọ.

← Isaiah 22 Isaiah Isaiah 24 →

Isaiah 23 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002