1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Babeli èyí tí Isaiah ọmọ Amosi rí.
2Gbé àsíá sókè ní orí òkè gbẹrẹfu,
3Mo ti pàṣẹ fún àwọn ẹni mímọ́ mi,
4Gbọ́ ohùn kan ní àwọn orí òkè,
5Wọ́n wá láti ọ̀nà jíjìn réré,
6Ẹ hu, nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ tòsí,
7Nítorí èyí, gbogbo ọwọ́ ni yóò rọ,
8Ẹ̀rù yóò gbá wọn mú,
9Kíyèsi i, ọjọ́ Olúwa ń bọ̀
10Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti ìkójọpọ̀ wọn
11Èmi yóò jẹ ayé ní ìyà nítorí ibi rẹ̀,
12Èmi yóò jẹ́ kí ọkùnrin kí ó wọn
13Nítorí náà èmi yóò jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó wárìrì;
14Gẹ́gẹ́ bí egbin tí à ń dọdẹ rẹ̀,
15Ẹnikẹ́ni tí a bá gbámú ni a ó wọ́ nílẹ̀ tuurutu,
16Àwọn ọ̀dọ́mọdé wọn ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn,
17Kíyèsi i, èmi yóò ru àwọn Media sókè sí wọn,
18Ọrùn wọn yóò ré àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin lulẹ̀;
19Babeli, ohun ọ̀ṣọ́ àwọn ìjọba
20A kì yóò tẹ̀ ibẹ̀ dó mọ́
21Ṣùgbọ́n àwọn ẹranko igbó ni yóò dùbúlẹ̀ níbẹ̀,
22Ìkookò yóò máa gbó ní ibùba wọn,