We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Amosi 3

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Amosi 2 Amosi Amosi 4 →

1Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Israẹli nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Ejibiti:

2“Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yàn

3Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀

4Ǹjẹ́ Kìnnìún yóò ha bú ramúramù nínú igbó,

5Ǹjẹ́ ẹyẹ ṣubú sínú okùn ọdẹ lórí ilẹ̀

6Nígbà tí ìpè bá dún ní ìlú,

7Nítòótọ́ Olúwa Olódùmarè kò ṣe ohun kan

8Kìnnìún ti bú ramúramù

9Ẹ kéde ní ààfin Aṣdodu

10“Wọn kò mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe rere,” ni Olúwa wí,

11Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:

12Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

13“Gbọ́ èyí kí o sì jẹ́rìí nípa ilé Jakọbu,” ni Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun.

14“Ní ọjọ́ tí mo fìyà jẹ Israẹli lórí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,

15Èmi yóò wó ilé òtútù

← Amosi 2 Amosi Amosi 4 →

Amosi 3 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002