We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Amosi 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Amosi 1 Amosi Amosi 3 →

1Èyí ni ohun tí Olúwa wí,

2Èmi yóò rán iná sí orí Moabu

3Èmi yóò ké onídàájọ́ rẹ̀ kúrò,

4Èyí ni ohun tí Olúwa wí,

5Èmi yóò rán iná sí orí Juda

6Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

7Wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ orí àwọn tálákà mọ́lẹ̀,

8Wọ́n dùbúlẹ̀ lẹ́bàá a pẹpẹ,

9“Mo pa àwọn ará Amori run níwájú wọn

10Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá,

11“Èmi sì tún gbé àwọn wòlíì dìde láàrín àwọn ọmọ yín

12“Ṣùgbọ́n ẹ̀yin fún àwọn Nasiri ní ọtí mu

13“Ní báyìí, èmi yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀

14Ẹni tí ó yára bí àṣá kò ní rí ọ̀nà àbáyọ

15Tafàtafà kì yóò dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀

16Àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọ

← Amosi 1 Amosi Amosi 3 →

Amosi 2 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002