We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Amosi 1

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

Amosi Amosi 2 →

1Àwọn ọ̀rọ̀ Amosi, ọ̀kan lára àwọn olùṣọ́-àgùntàn Tekoa; ohun tí o rí nípa Israẹli ní ọdún méjì ṣáájú ilẹ̀-rírì, nígbà tí Ussiah ọba Juda àti Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi jẹ́ ọba ní ilẹ̀ Israẹli.

2Ó wí pé,

3Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

4Èmi yóò rán iná sí ilé Hasaeli,

5Èmi yóò ṣẹ́ ọ̀pá ìdábùú Damasku;

6Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

7Èmi yóò rán iná sí ara odi Gasa

8Èmi yóò ké àwọn olùgbé Aṣdodu kúrò,

9Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

10Èmi yóò rán iná sí ara odi Tire,

11Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

12Èmi yóò rán iná sí orí Temani,

13Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

14Èmi yóò rán iná sí ara odi Rabba

15Ọba wọn yóò sì lọ sí ìgbèkùn,

Amosi Amosi 2 →

Amosi 1 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002