We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Saamu 6

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Saamu 5 Saamu Saamu 7 →

1Olúwa, má ṣe bá mi wí nínú ìbínú rẹ

2Ṣàánú fún mi, Olúwa, nítorí èmi ń kú lọ;

3Ọkàn mi wà nínú ìrora.

4Yípadà, Olúwa, kí o sì gbà mí;

5Ẹnikẹ́ni kò ni rántí rẹ nígbà tí ó bá kú.

6Agara ìkérora mi dá mi tán.

7Ojú mi di aláìlera pẹ̀lú ìbànújẹ́;

8Kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe iṣẹ́ ibi,

9Olúwa ti gbọ́ ẹkún mi fún àánú;

10Gbogbo àwọn ọ̀tá mi lójú yóò tì, wọn yóò sì dààmú;

← Saamu 5 Saamu Saamu 7 →

Saamu 6 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002