1Ti Olúwa ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún rẹ̀,
2nítorí ó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀ lórí òkun
3Ta ni yóò gun orí òkè Olúwa lọ?
4Ẹni tí ó ní ọwọ́ mímọ́ àti àyà funfun,
5Òun ni yóò rí ìbùkún gbà láti ọ̀dọ̀ Olúwa,
6Èyí ni ìran àwọn tí ń ṣe àfẹ́rí rẹ̀,
7Ẹ gbé orí yín sókè, háà! Ẹ̀yin ọ̀nà;
8Ta ni ọba ògo náà?
9Gbé orí yín sókè, ẹyin ọ̀nà;
10Ta ni Ọba ògo náà?