We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Hosea 8

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Hosea 7 Hosea Hosea 9 →

1“Fi ìpè sí ẹnu rẹ!

2Israẹli kígbe pè mí,

3Ṣùgbọ́n Israẹli ti kọ ohun tí ó dára sílẹ̀

4Wọ́n fi àwọn ọba jẹ ṣùgbọ́n, kì í ṣe nípasẹ̀ mi

5Ju ère ẹgbọrọ màlúù rẹ, ìwọ Samaria!

6Israẹli ni wọ́n ti wá!

7“Wọ́n gbin afẹ́fẹ́

8A ti gbé Israẹli mì,

9Nítorí pé wọ́n ti gòkè lọ sí Asiria

10Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti ta ara wọn sí àárín Orílẹ̀-èdè,

11“Nítorí Efraimu ti kọ́ pẹpẹ púpọ̀ fún ìrúbọ ẹ̀ṣẹ̀

12Mo kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun tí ó jẹ́ òfin mi fún wọn,

13Wọ́n ń rú ẹbọ tí wọ́n yàn fún mi,

14Nítorí Israẹli ti gbàgbé ẹlẹ́dàá rẹ̀

← Hosea 7 Hosea Hosea 9 →

Hosea 8 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002