We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Hosea 4

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Hosea 3 Hosea Hosea 5 →

1Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa ẹ̀yin ọmọ Israẹli,

2àfi èpè, irọ́ pípa àti ìpànìyàn

3Nítorí èyí, ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀,

4“Ṣùgbọ́n kí ẹnikẹ́ni má ṣe mú ẹ̀sùn wá,

5Ẹ ń ṣubú lọ́sàn án àti lóru

6àwọn ènìyàn mi ń ṣègbé nítorí pé wọn kò ní ìmọ̀.

7Bí àwọn àlùfáà ṣe ń pọ̀ sí i

8wọ́n ń jẹun nípa ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn mi,

9Yóò sì ṣe gẹ́gẹ́ bí ènìyàn ṣe rí náà ni àwọn àlùfáà rí.

10“Wọn ó máa jẹun ṣùgbọ́n wọn kò ní yó;

11fún àgbèrè;

12Wọ́n ń gba ìmọ̀ràn lọ́wọ́ ère igi

13Wọ́n ń rú ẹbọ lórí àwọn òkè ńlá,

14“Èmi kò ní jẹ àwọn ọmọbìnrin yín

15“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o ṣe àgbèrè ìwọ Israẹli,

16Àwọn ọmọ Israẹli ṣe agídí

17Efraimu ti darapọ̀ mọ́

18Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tán,

19Ìjì ni yóò gbá wọn lọ.

← Hosea 3 Hosea Hosea 5 →

Hosea 4 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002