1Israẹli jẹ́ igi àjàrà tó gbilẹ̀
2Ọkàn wọn kún fún ìtànjẹ
3Nígbà náà ni wọn yóò wí pé, “A kò ní ọba
4Wọ́n ṣe ìlérí púpọ̀,
5Àwọn ènìyàn tí ń gbé Samaria bẹ̀rù
6A ó gbé lọ sí Asiria
7Bí igi tó léfòó lórí omi ni
8Àwọn ibi gíga tí ẹ tí ń hùwà búburú ni a o parun,
9“Láti ìgbà Gibeah, ni ó ti ṣẹ̀, ìwọ Israẹli,
10Nígbà tó bá tẹ́ mi lọ́rùn, èmi yóò fi ìyà jẹ wọ́n;
11Efraimu jẹ́ ọmọ abo màlúù tí a tí kọ́,
12Ẹ gbin òdòdó fún ara yín,
13Ṣùgbọ́n ẹ tí gbin búburú ẹ si ka ibi,
14ariwo ogun yóò bo àwọn ènìyàn yín
15Báyìí ni a o sì ṣe sí ọ, ìwọ Beteli,