We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 56

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 55 Isaiah Isaiah 57 →

1Èyí ni ohun ti Olúwa sọ:

2Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ó ṣe èyí,

3Má ṣe jẹ́ kí àjèjì kan tí ó ti di ara rẹ̀

4Nítorí pé báyìí ni Olúwa wí:

5fún wọn ni Èmi yóò fún nínú tẹmpili àti àgbàlá rẹ̀

6Àti àwọn àjèjì tí ó so ara wọn mọ́ Olúwa

7àwọn wọ̀nyí ni èmi yóò mú wá òkè mímọ́ mi,

8Olúwa Olódùmarè sọ wí pé—

9Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin ẹranko inú pápá,

10Àwọn olùṣọ́ Israẹli fọ́jú,

11Wọ́n jẹ́ àwọn ajá tí ó kúndùn púpọ̀;

12Igbe ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ni wí pé, “Wá, fún mi ní ọtí wáìnì!

← Isaiah 55 Isaiah Isaiah 57 →

Isaiah 56 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002