1“Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òǹgbẹ ń gbẹ,
2Èéṣe tí ẹ fi ń ná owó fún èyí tí kì í ṣe àkàrà
3Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi;
4Kíyèsi i, mo ti fi òun ṣe ẹlẹ́rìí fún àwọn ènìyàn,
5Lóòtítọ́ ìwọ yóò ké sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò mọ̀
6Ẹ wá Olúwa nígbà tí ẹ lè rí i;
7Jẹ́ kí ìkà kí ó kọ ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀
8“Nítorí èrò mi kì í ṣe èrò yín,
9“Gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti ga ju ayé lọ,
10Gẹ́gẹ́ bí òjò àti yìnyín
11bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tí ó jáde láti ẹnu mi wá;
12Ẹ̀yin yóò jáde lọ ní ayọ̀
13Dípò igi ẹ̀gún ni igi junifa yóò máa dàgbà,