We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 28

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 27 Isaiah Isaiah 29 →

1Ègbé ni fún adé ìgbéraga,

2Kíyèsi i, Olúwa ní ẹnìkan tí ó le, tí ó sì lágbára,

3Adé ìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Efraimu,

4Òdòdó tí ó ń rọ náà tí í ṣe ẹwà ògo rẹ̀,

5Ní ọjọ́ náà Olúwa àwọn ọmọ-ogun

6Òun yóò sì jẹ́ ẹ̀mí ìdájọ́ òdodo

7Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n fún ọtí wáìnì

8Gbogbo orí tábìlì ni ó kún fún èébì

9“Ta ni ẹni náà tí ó ń gbìyànjú àti kọ́?

10Nítorí tí í ṣe: báyìí ni orí,

11Ó dára báyìí, pẹ̀lú ètè àjèjì àti ahọ́n àìmọ̀

12àwọn tí ó sọ fún wí pé,

13Fún ìdí èyí, ọ̀rọ̀ Olúwa sí wọn yóò di pé,

14Nítorí náà, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, ẹ̀yin ẹlẹ́gàn,

15Ẹ fọ́n pé, “Àwa ti bá ikú mulẹ̀,

16Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:

17Èmi yóò fi ìdájọ́ ṣe okùn òsùwọ̀n

18Májẹ̀mú yín tí ẹ bá ikú dá ni a ó fa igi lé;

19Nígbàkígbà tí ó bá ti wá ni

20Ibùsùn kúrú púpọ̀ fún ìnara lé lórí,

21Olúwa yóò dìde sókè gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe

22Ní ìsinsin yìí ẹ dákẹ́ ẹlẹ́yà ṣíṣe,

23Tẹ́tí kí o sì gbọ́ ohùn mi,

24Nígbà tí àgbẹ̀ kan bá tu ilẹ̀ láti gbìn

25Nígbà tí òun bá ti tẹ́ ojú ilẹ̀ rẹ̀ pẹrẹsẹ

26Ọlọ́run rẹ̀ tọ́ ọ ṣọ́nà

27Nítorí a kò fi ohun èlò ìpakà dili,

28A gbọdọ̀ lọ ìyẹ̀fun kí a tó ṣe àkàrà;

29Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wá,

← Isaiah 27 Isaiah Isaiah 29 →

Isaiah 28 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002