We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 21

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 20 Isaiah Isaiah 22 →

1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan aginjù lẹ́bàá Òkun.

2Ìran tí a ń fojú ṣọ́nà fún ni a ti fihàn mí

3Pẹ̀lú èyí, ìrora mu mi lára gírígírí,

4Ọkàn mí dàrú,

5Wọ́n tẹ́ tábìlì,

6Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi:

7Nígbà tí ó bá rí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun

8Òun sì kígbe pé, kìnnìún kan,

9Wò ó, ọkùnrin kan ni ó ń bọ̀ wá yìí nínú kẹ̀kẹ́ ogun

10Ẹ̀yin ènìyàn mi, tí a gún mọ́lẹ̀ ní ilẹ̀ ìpakà,

11Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Dumahi.

12Alóre náà dáhùn wí pé,

13Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Arabia.

14gbé omi wá fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹ;

15Wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ idà,

16Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi: “Láàrín ọdún kan, gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀fà tí ó wà lábẹ́ ọgbà, í ti í kà á, gbogbo ògo ìlú Kedari yóò wá sí òpin.

17Àwọn tafàtafà tí ó sálà, àwọn jagunjagun ìlú Kedari kò ní tó nǹkan.” Olúwa, Ọlọ́run Israẹli ni ó ti sọ̀rọ̀.

← Isaiah 20 Isaiah Isaiah 22 →

Isaiah 21 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002