We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 15

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 14 Isaiah Isaiah 16 →

1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Moabu,

2Diboni gòkè lọ sí tẹmpili rẹ̀,

3Wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀ ní ojú òpópónà,

4Heṣboni àti Eleale ké sóde,

5Ọkàn mi kígbe sókè lórí Moabu;

6Gbogbo omi Nimrimu ni ó ti gbẹ

7Báyìí gbogbo ọrọ̀ tí wọ́n ti ní tí wọ́n sì tò jọ

8Gbohùngbohùn ń gba igbe wọn dé ìpẹ̀kun ilẹ̀ Moabu;

9Omi Dimoni kún fún ẹ̀jẹ̀,

← Isaiah 14 Isaiah Isaiah 16 →

Isaiah 15 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002