We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Amosi 6

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Amosi 5 Amosi Amosi 7 →

1Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ará rọ̀ ní Sioni

2Ẹ lọ Kalne kí ẹ lọ wò ó

3Ẹ̀yin sún ọjọ́ ibi síwájú,

4Ẹ̀yin sùn lé ibùsùn tí a fi eyín erin ṣe

5Ẹ̀yin ń lo ohun èlò orin bí i Dafidi

6Ẹ̀yin mu wáìnì ẹ̀kún ọpọ́n kan

7Nítorí náà, àwọn ni yóò lọ sí ìgbèkùn

8Olúwa Olódùmarè ti búra fúnra rẹ̀, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun sì ti wí pé:

9Bí ọkùnrin mẹ́wàá bá ṣẹ́kù nínú ilé kan, àwọn náà yóò kú.

10Bí ẹbí tí ó yẹ kí ó gbé òkú wọn jáde fún sínsin bá wọlé, bí o ba sì béèrè pé ǹjẹ́ ẹnìkan wa tí ó fi ara pamọ́ níbẹ̀, “Ǹjẹ́ ẹnìkankan wà lọ́dọ̀ yín?” tí ó bá sì dáhùn wí pé, “Rárá,” nígbà náà ni yóò wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́ àwa kò gbọdọ̀ dárúkọ Olúwa.”

11Nítorí Olúwa tí pa àṣẹ náà,

12Ǹjẹ́ ẹṣin a máa sáré lórí àpáta bí?

13Ẹ̀yin yọ̀ torí ìṣẹ́gun lórí Lo-Debari,

14Nítorí Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun wí pé,

← Amosi 5 Amosi Amosi 7 →

Amosi 6 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002