We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Saamu 16

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Saamu 15 Saamu Saamu 17 →

1Pa mí mọ́, Ọlọ́run,

2Mo sọ fún Olúwa, “Ìwọ ni Olúwa mi,

3Sí àwọn ènìyàn tí ó wà ní ayé,

4Ìṣòro àwọn wọ̀n-ọn-nì yóò pọ̀ sí i, àní àwọn tí ń tọ ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn.

5Olúwa, ni ìpín ìní mi tí mo yàn àti ago mi,

6Okùn ààlà ilẹ̀ ti bọ́ sí ọ̀dọ̀ mi ní ibi dídára;

7Èmi yóò yin Olúwa, ẹni tí ó gbà mí ní ìyànjú;

8Mo ti gbé Olúwa síwájú mi ní ìgbà gbogbo.

9Nítorí èyí, ọkàn mi yọ̀, ahọ́n mi pẹ̀lú ń fò fáyọ̀;

10nítorí ìwọ kò ní fi ọ̀kan sílẹ̀ nínú isà òkú,

11Ìwọ ti fi ipa ọ̀nà ìyè hàn mí;

← Saamu 15 Saamu Saamu 17 →

Saamu 16 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002