1Èmi yóò yìn ọ́ tinútinú mi gbogbo;
2Èmi ó máa gbàdúrà sí ìhà tẹmpili mímọ́ rẹ̀
3Ní ọjọ́ tí mo ké pè é ọ́, ìwọ dá mi lóhùn,
4Gbogbo àwọn ọba ayé yóò yìn ọ́,
5Nítòótọ́, wọn ó máa kọrin ní ipa ọ̀nà Olúwa;
6Bí Olúwa tilẹ̀ ga, síbẹ̀ ó júbà àwọn onírẹ̀lẹ̀;
7Bí èmi tilẹ̀ ń rìn nínú ìpọ́njú ìwọ ni yóò sọ mi di ààyè;
8Olúwa yóò ṣe ohun tí ń ṣe tèmi láṣepé;