We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Sefaniah 1

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

Sefaniah Sefaniah 2 →

1Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Sefaniah ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedaliah, ọmọ Amariah, ọmọ Hesekiah, ní ìgbà Josiah ọmọ Amoni ọba Juda.

2“Èmi yóò mú gbogbo nǹkan kúrò

3“Èmi yóò mú ènìyàn àti ẹranko kúrò;

4“Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Juda

5àti àwọn tí ń foríbalẹ̀ lórí òrùlé,

6Àwọn tí ó yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa;

7Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa Olódùmarè,

8“Ní ọjọ́ ẹbọ Olúwa,

9Ní ọjọ́ náà, èmi yóò fi ìyà jẹ

10“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí,

11Ẹ hu, ẹ̀yin tí ń gbé ní agbègbè ọjà,

12Ní àkókò wọ̀n-ọn-nì, èmi yóò wá Jerusalẹmu kiri pẹ̀lú fìtílà,

13Nítorí náà, ọrọ̀ wọn yóò di ìkógun,

14“Ọjọ́ ńlá Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀,

15ọjọ́ náà yóò jẹ́ ọjọ́ ìbínú,

16ọjọ́ ìpè àti ìpè ogun

17“Èmi yóò sì mú ìpọ́njú wá sórí ènìyàn,

18Bẹ́ẹ̀ ni fàdákà tàbí wúrà wọn

Sefaniah Sefaniah 2 →

Sefaniah 1 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002