We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Hosea 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Hosea 1 Hosea Hosea 3 →

1“Sọ fún àwọn arákùnrin rẹ, ‘Ènìyàn mi,’ kí o sì wí fún àwọn arábìnrin rẹ ‘Àyànfẹ́ mi.’

2“Ẹ bá ìyá yín wí, ẹ bá a wí,

3Àìṣe bẹ́ẹ̀ èmi yóò tú u sí ìhòhò,

4Èmi kò ní fi àánú mi hàn sí àwọn ọmọ rẹ̀

5Nítorí ìyá wọn ti hùwà àgbèrè,

6Nítorí náà, èmi ó fi ẹ̀gún dì í lọ́nà,

7Yóò sáré lé àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ṣùgbọ́n kò ní bá wọn;

8Nítorí pé kò tí ì mọ̀ pé èmi ni

9“Nítorí náà, èmi yóò mú ọkà mi kúrò nígbà tó bá pọ́n,

10Èmi yóò sì fi ìwà ìtìjú rẹ̀ hàn

11Èmi yóò mú gbogbo ayọ̀ rẹ̀ wá sí òpin:

12Èmi yóò pa àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀ run,

13Èmi yóò bẹ̀ ọjọ́ Baalimu wò ní ara rẹ̀

14“Nítorí náà, èmi yóò tàn án,

15Níbẹ̀ ni èmi yóò ti dá ọgbà àjàrà rẹ̀ padà fún un,

16“Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà,

17Èmi yóò mú orúkọ, àwọn òrìṣà Baali kúrò lẹ́nu rẹ̀;

18Ní ọjọ́ náà, èmi yóò ṣe májẹ̀mú

19Èmi yóò fẹ́ ọ fún ara mi títí láé;

20Èmi yóò fẹ́ ọ fún ara mi ní òtítọ́

21“Èmi yóò sì dáhùn ní ọjọ́ náà,”

22ilẹ̀ náà yóò sì dá ọkà,

23Èmi ó sì gbìn ín fún ara mi lórí ilẹ̀ náà,

← Hosea 1 Hosea Hosea 3 →

Hosea 2 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002