We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Jobu 21

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Jobu 20 Jobu Jobu 22 →

1Jobu wá dáhùn, ó sì wí pé,

2“Ẹ tẹ́tí sílẹ̀ dáradára sì àwọn ọ̀rọ̀ mi,

3Ẹ jọ̀wọ́ mi ki èmi sọ̀rọ̀;

4“Àròyé mi ha ṣe sí ènìyàn bí?

5Ẹ wò mí fín, kí ẹnu kí ó sì yà yín,

6Àní nígbà tí mo rántí, ẹ̀rù bà mí,

7Nítorí kí ní ènìyàn búburú fi wà ní ayé,

8Irú-ọmọ wọn fi ìdí kalẹ̀ ní ojú

9Ilé wọn wà láìní ewu àti ẹ̀rù,

10Akọ màlúù wọn a máa gùn, kì í sì tàsé;

11Wọn a máa rán àwọn ọmọ wọn

12Wọ́n mú ohun ọ̀nà orin, ìlù àti haapu;

13Wọ́n n lo ọjọ́ wọn nínú ọrọ̀;

14Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa!’

15Kí ni Olódùmarè tí àwa ó fi máa sìn in?

16Kíyèsi i, àlàáfíà wọn kò sí nípa ọwọ́ wọn;

17“Ìgbà mélòó mélòó ní a ń pa fìtílà ènìyàn búburú kú?

18Wọ́n dàbí àgékù koríko níwájú afẹ́fẹ́,

19Ẹ̀yin wí pé, ‘Ọlọ́run to ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jọ fún àwọn ọmọ rẹ̀.’

20Ojú rẹ̀ yóò rí ìparun ara rẹ̀,

21Nítorí pé àlàáfíà kí ni ó ní nínú ilé rẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀,

22“Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni le kọ Ọlọ́run ní ìmọ̀?

23Ẹnìkan a kú nínú pípé agbára rẹ̀,

24Ọpọ́n rẹ̀ kún fún omi ọmú,

25Ẹlòmíràn a sì kú nínú kíkorò ọkàn rẹ̀,

26Wọ́n o dùbúlẹ̀ bákan náà nínú erùpẹ̀,

27“Kíyèsi i, èmi mọ̀ èrò inú yín àti

28Nítorí tí ẹ̀yin wí pé, ‘Níbo ní ilé ọmọ-aládé,

29Ẹ̀yin kò béèrè lọ́wọ́ àwọn tí ń kọjá lọ ní ọ̀nà?

30pé ènìyàn búburú ní a fi pamọ́ fún ọjọ́ ìparun.

31Ta ni yóò tako ipa ọ̀nà rẹ̀ lójúkojú,

32Síbẹ̀ a ó sì sin ín ní ọ̀nà ipò òkú,

33Ògúlùtu àfonífojì yóò dùn mọ́ ọn.

34“Èéha ti ṣe tí ẹ̀yin fi ń tù mí nínú lásán,

← Jobu 20 Jobu Jobu 22 →

Jobu 21 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002