We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Jeremiah 30

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Jeremiah 29 Jeremiah Jeremiah 31 →

1Ọ̀rọ̀ tí ó tọ Jeremiah wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá, wí pé:

2“Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Israẹli wí, pé: ‘Ìwọ kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ti bá ọ sọ sínú ìwé kan.

3Ọjọ́ ń bọ̀ nígbà tí ń ó mú àwọn ènìyàn mi, àwọn ọmọ Israẹli àti Juda kúrò nínú ìgbèkùn, tí n ó sì dá wọn padà sí orí ilẹ̀ tí mo fi fún àwọn baba ńlá wọn láti ní,’ ni Olúwa Ọlọ́run wí.”

4Ìwọ̀nyí ni àwọn ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run sí Israẹli àti Juda:

5“Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

6Béèrè kí o sì rí.

7Ọjọ́ náà yóò ha ti burú tó!

8“ ‘Ní ọjọ́ náà,’ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé,

9Dípò bẹ́ẹ̀ wọn yóò máa sin Olúwa Ọlọ́run wọn

10“ ‘Nítorí náà, má ṣe bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu ìránṣẹ́ mi,

11Èmi wà pẹ̀lú rẹ, n ó sì gbà ọ́,’

12“Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

13Kò sí ẹnìkan tí yóò bẹ̀bẹ̀ fún àìṣedéédéé yín,

14Gbogbo àwọn olùfẹ́ rẹ ti gbàgbé rẹ,

15Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń kígbe nítorí ọgbẹ́ yín,

16“ ‘Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ṣe yín ní ibi ni ibi yóò bá,

17Ṣùgbọ́n èmi yóò fi ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìlera fún yín,

18“Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

19Láti ẹnu wọn ni orin ọpẹ́ àti

20Ọmọ ọmọ wọn yóò wà bí i ti ìgbàanì

21Ọ̀kan nínú wọn ni yóò jẹ́ olórí wọn,

22‘Nítorí náà, ẹ̀yin yóò jẹ́ ènìyàn mi,

23Wò ó, ìbínú Olúwa yóò tú jáde,

24Ìbínú ńlá Olúwa kò ní dẹ̀yìn lẹ́yìn

← Jeremiah 29 Jeremiah Jeremiah 31 →

Jeremiah 30 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002