We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Jeremiah 15

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Jeremiah 14 Jeremiah Jeremiah 16 →

1Nígbà náà ni Olúwa sọ fún mi pé: “Kódà kí Mose àti Samuẹli dúró níwájú mi, ọkàn mi kì yóò lọ sọ́dọ̀ àwọn ènìyàn wọ̀nyí. Mú wọn kúrò níwájú mi! Jẹ́ kí wọn ó lọ!

2Tí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Níbo ni kí a lọ?’ Sọ fún wọn pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí:

3“Èmi yóò rán oríṣìí ìjìyà mẹ́rin láti kọlù wọ́n,” ni Olúwa wí, “Idà láti pa, àwọn ajá láti wọ́ wọn lọ, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹranko orí ilẹ̀ láti jẹ àti láti parun.

4N ó sọ wọ́n di ẹni ìkórìíra níwájú gbogbo ìjọba ayé torí ohun tí Manase ọmọ Hesekiah ọba Juda ṣe ní Jerusalẹmu.

5“Ta ni yóò ṣàánú rẹ, ìwọ Jerusalẹmu?

6O ti kọ̀ mí sílẹ̀,” ni Olúwa wí,

7Èmi kò tún lè fi ìfẹ́ hàn si ọ,

8Èmi yóò jẹ́ kí àwọn opó wọn pọ̀ ju

9Ìyá ọlọ́mọ méje yóò dákú,

10Háà! Ó ṣe tí ìyá mi bí mi,

11Olúwa sọ pé,

12“Ǹjẹ́ ẹnìkan lè fi ọwọ́ ṣẹ́ irin

13“Gbogbo ọlá àti ìṣúra rẹ

14Èmi yóò fi ọ́ ṣẹrú fún àwọn ọ̀tá rẹ

15Ó yé ọ, ìwọ Olúwa;

16Nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ dé, mo jẹ wọ́n,

17Èmi kò fìgbà kan jókòó láàrín àwọn ẹlẹ́gàn,

18Èéṣe tí ìrora mi kò lópin,

19Nítorí náà báyìí ni Olúwa wí,

20Èmi fi ọ́ ṣe odi idẹ tí ó lágbára,

21“Èmi yóò gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ìkà ènìyàn,

← Jeremiah 14 Jeremiah Jeremiah 16 →

Jeremiah 15 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002