We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Jona 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Jona 1 Jona Jona 3 →

1Nígbà náà ni Jona gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ láti inú ẹja náà wá,

2Ó sì wí pé:

3Nítorí tí ìwọ ti sọ mí sínú ibú,

4Nígbà náà ni mo wí pé,

5Omi yí mi káàkiri, àní títí dé ọkàn;

6Èmi sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ àwọn òkè ńlá;

7“Nígbà tí ó rẹ ọkàn mi nínú mi,

8“Àwọn tí ń fàmọ́ òrìṣà èké

9Ṣùgbọ́n èmi yóò fi orin ọpẹ́, rú ẹbọ sí ọ.

10Olúwa sì pàṣẹ fún ẹja náà, ó sì pọ Jona sí orí ilẹ̀ gbígbẹ.

← Jona 1 Jona Jona 3 →

Jona 2 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002