We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Joẹli 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Joẹli 1 Joẹli Joẹli 3 →

1Ẹ fun ìpè ní Sioni,

2Ọjọ́ òkùnkùn àti ìrọ́kẹ̀kẹ̀,

3Iná ń jó níwájú wọ́n;

4Ìrí wọn dàbí ìrí àwọn ẹṣin;

5Bí ariwo kẹ̀kẹ́ ogun ni

6Ní ojú wọn, àwọn ènìyàn yóò jẹ ìrora púpọ̀:

7Wọn yóò sáré bi àwọn alágbára;

8Bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kì yóò kọlu ẹnìkejì rẹ̀;

9Wọn yóò sáré síwá sẹ́yìn ní ìlú;

10Ayé yóò mì níwájú wọn;

11Olúwa yóò sì bú ramúramù

12“Ǹjẹ́ nítorí náà nísinsin yìí,” ni Olúwa wí,

13Ẹ sì fa ọkàn yín ya,

14Ta ni ó mọ̀ bí òun yóò yípadà, kí o sì ronúpìwàdà,

15Ẹ fún ìpè ní Sioni,

16Ẹ kó àwọn ènìyàn jọ,

17Jẹ́ kí àwọn àlùfáà, àwọn ìránṣẹ́ Olúwa,

18Nígbà náà ní Olúwa yóò jowú fún ilẹ̀ rẹ̀,

19Nítòótọ́, Olúwa yóò dá wọn lóhùn, yóò sì wí fun àwọn ènìyàn rẹ̀ pé:

20“Ṣùgbọ́n èmi yóò lé ogun àríwá jìnnà réré kúrò lọ́dọ̀ yín,

21Má bẹ̀rù, ìwọ ilẹ̀;

22Ẹ má bẹ̀rù, ẹranko igbó,

23Ẹ jẹ́ kí inú yín dùn, ẹ̀yin ọmọ Sioni,

24Àwọn ilẹ̀ ìpakà yóò kún fún ọkà;

25“Èmi yóò sì mú ọdún wọ̀nyí ti eṣú jẹ run padà fún un yín.

26Ẹ̀yin yóò ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti jẹ, títí ẹ̀yin yóò fi yó

27Ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, èmi wà láàrín Israẹli,

28“Yóò sì ṣe níkẹyìn ọjọ́,

29Àti pẹ̀lú sí ara àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ ọkùnrin,

30Èmi yóò sì fi iṣẹ́ ìyanu hàn ní ọrun

31A á sọ oòrùn di òkùnkùn,

32Yóò sí ṣe, ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pè

← Joẹli 1 Joẹli Joẹli 3 →

Joẹli 2 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002