1“Ǹjẹ́ nítorí náà, Jobu, èmí bẹ̀ ọ,
2Kíyèsi i nísinsin yìí, èmí ya ẹnu mi,
3Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi,
4Ẹ̀mí Ọlọ́run ni ó tí dá mi,
5Bí ìwọ bá le dá mi lóhùn,
6kíyèsi i, bí ìwọ ṣe jẹ́ ti Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà;
7Kíyèsi i, ẹ̀rù ńlá mi kì yóò bà ọ;
8“Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi,
9‘Èmi mọ́, láìní ìrékọjá, aláìṣẹ̀ ní èmi;
10Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi;
11Ó kan ẹ̀ṣẹ̀ mi sínú àbà;
12“Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà!
13Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé,
14Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan,
15Nínú àlá, ní ojúran òru,
16nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn,
17kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀;
18Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú,
19“A sì nà án lórí ibùsùn ìrora rẹ̀;
20bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mí rẹ kọ oúnjẹ,
21Ẹran-ara rẹ̀ run, títí a kò sì fi lè rí i mọ́
22Àní, ọkàn rẹ̀ sì súnmọ́ isà òkú,
23Bí angẹli kan ba wà lọ́dọ̀ rẹ̀,
24nígbà náà ni ó ṣe oore-ọ̀fẹ́ fún un ó sì wí pé,
25Ara rẹ̀ yóò sì di ọ̀tun bí i ti ọmọ kékeré,
26Ó gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun sì ṣe ojúrere rẹ̀,
27Ó wá sọ́dọ̀ ènìyàn ó sì wí pé,
28Ọlọ́run ti gba ọkàn mi kúrò nínú lílọ sínú ihò,
29“Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́run
30láti mú ọkàn rẹ padà kúrò nínú isà òkú,
31“Jobu, kíyèsi i gidigidi, kí o sì fetí sí mi;
32Bí ìwọ bá sì ní ohun wí, dá mi lóhùn;
33Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, gbọ́ tèmi;