1“Dìde, tànmọ́lẹ̀, nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé,
2Kíyèsi i, òkùnkùn bo ilẹ̀ ayé
3Àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá sí ìmọ́lẹ̀ rẹ,
4“Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò.
5Nígbà náà ni ìwọ yóò wò tí ojú rẹ yóò máa dán,
6Ọ̀wọ́ ìbákasẹ yóò bo gbogbo ilẹ̀ rẹ,
7Gbogbo agbo ẹran ìlú Kedari ni a ó kójọ sọ́dọ̀ rẹ,
8“Ta ni àwọn wọ̀nyí tí ń fò lọ bí i kurukuru,
9Lóòtítọ́ àwọn erékùṣù bojú wò mí;
10“Àwọn àjèjì yóò tún ògiri rẹ mọ
11Gbogbo ẹnu-bodè rẹ ni yóò wà ní ṣíṣí sílẹ̀,
12Nítorí pé orílẹ̀-èdè tàbí ilẹ̀ ọba tí kì yóò sìn ọ́ ni yóò parun;
13“Ògo Lebanoni yóò wá sí ọ̀dọ̀ rẹ,
14Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àwọn apọ́nilójú rẹ yóò
15“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kórìíra rẹ, a sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀,
16Ìwọ yóò mu wàrà gbogbo orílẹ̀-èdè
17Dípò idẹ, èmi ó mú wúrà wá fún ọ,
18A kì yóò gbọ́ nípa rògbòdìyàn ní ilẹ̀ rẹ mọ́,
19Òòrùn kì yóò sì jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ní ọ̀sán mọ́,
20Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́,
21Lẹ́yìn náà ni gbogbo àwọn ènìyàn rẹ yóò di òdodo
22Èyí tí ó kéré jù nínú yín yóò di ẹgbẹ̀rún (1,000) kan,