1Ta ni ó ti gba ìròyìn in wa gbọ́
2Òun dàgbàsókè níwájú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ irúgbìn,
3A kẹ́gàn rẹ̀ àwọn ènìyàn sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀,
4Lóòtítọ́ ó ti ru àìlera wa lọ
5Ṣùgbọ́n a sá a lọ́gbẹ́ nítorí àìṣedéédéé wa
6Gbogbo wa bí àgùntàn, ti ṣìnà lọ,
7A jẹ ẹ́ ní yà, a sì pọ́n ọn lójú,
8Pẹ̀lú ìpọ́nlójú àti ìdánilẹ́jọ́ ni a mú un jáde lọ,
9A fún un ní ibojì pẹ̀lú àwọn ìkà,
10Síbẹ̀, ó wu Olúwa láti pa á lára
11Lẹ́yìn ìpọ́njú ẹ̀mí rẹ̀,
12Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńlá