1Ẹ tù ú nínú, ẹ tu ènìyàn mi nínú,
2Sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ fún Jerusalẹmu
3Ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù:
4Gbogbo àfonífojì ni a ó gbé sókè,
5Ògo Olúwa yóò sì di mí mọ̀,
6Ohùn kan wí pé, “Kígbe sókè.”
7Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀,
8Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀,
9Ìwọ tí o mú ìyìn ayọ̀ wá sí Sioni,
10Wò ó, Olúwa Olódùmarè náà ń bọ̀ wá pẹ̀lú agbára,
11Ó ń tọ́ àwọn agbo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn:
12Ta ni ó tiwọn omi nínú kòtò ọwọ́ rẹ̀,
13Ta ni ó ti mọ ọkàn Olúwa,
14Ta ni Olúwa ké sí kí ó là á lọ́yẹ
15Nítòótọ́ àwọn orílẹ̀-èdè dàbí i ẹ̀kún omi nínú garawa;
16Lebanoni kò tó fún pẹpẹ iná,
17Níwájú rẹ̀ ni gbogbo orílẹ̀-èdè dàbí ohun tí kò sí;
18Ta ni nígbà náà tí ìwọ yóò fi Ọlọ́run wé?
19Ní ti ère, oníṣọ̀nà ni ó dà á,
20Ọkùnrin kan tí ó tálákà jù kí ó lè mú
21Ǹjẹ́ o kò tí ì mọ̀
22Òun jókòó lórí ìtẹ́ ní òkè òbírí ilẹ̀ ayé,
23Ó sọ àwọn ọmọ ọba di asán
24Gẹ́rẹ́ tí a ti gbìn wọ́n,
25“Ta ni ẹ ó fi mi wé?
26Gbé ojú rẹ sókè kí o sì wo àwọn ọ̀run.
27Èéṣe tí o fi sọ, ìwọ Jakọbu?
28Ìwọ kò tí ì mọ̀?
29Ó ń fi agbára fún àwọn aláàárẹ̀
30Àní, ó ń rẹ̀ wọ́n àwọn ọ̀dọ́, wọ́n ń rẹ̀wẹ̀sì,
31ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwa