1Súnmọ́ tòsí,
2Nítorí ìbínú Olúwa ń bẹ
3Àwọn ti a pa nínú wọn
4Gbogbo àwọn ogun ọ̀run ni yóò di yíyọ́,
5Nítorí ti a rẹ idà mi ní ọ̀run,
6Idà Olúwa kún fún ẹ̀jẹ̀
7Àti àwọn àgbáǹréré yóò
8Nítorí ọjọ́ ẹ̀san Olúwa ni,
9Odò rẹ̀ ni a ó sì sọ di ọ̀dà,
10A kì yóò pa á ní òru tàbí ní ọ̀sán;
11Òwìwí aginjù, àti àkàlà ni yóò ni ín,
12Ní ti àwọn ìjòyè rẹ̀
13Ẹ̀gún yóò sì hù jáde
14Àwọn ẹranko ijù àti àwọn ìkookò ni yóò pàdé,
15Òwìwí yóò tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ síbẹ̀,
16Ẹ wo ìwé Olúwa, kí ẹ sì kà.
17Ó ti di ìbò fún wọn,