We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Isaiah 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Isaiah 1 Isaiah Isaiah 3 →

1Èyí ni ohun tí Isaiah ọmọ Amosi rí nípa Juda àti Jerusalẹmu.

2Ní ìgbẹ̀yìn ọjọ́

3Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn yóò sì wí pé,

4Òun ó ṣe ìdájọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,

5Wá, ẹ̀yìn ará ilé e Jakọbu,

6Ìwọ ti kọ àwọn ènìyàn rẹ sílẹ̀,

7Ilẹ̀ wọn kún fún fàdákà àti wúrà,

8Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ère,

9Nítorí náà ni a ó ṣe rẹ ènìyàn sílẹ̀

10Wọ inú àpáta lọ,

11Ojú agbéraga ènìyàn ni a ó rẹ̀ sílẹ̀

12Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan ní ìpamọ́

13nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó

14nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá

15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga

16fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò

17Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba

18gbogbo ère òrìṣà yóò pòórá.

19Àwọn ènìyàn yóò sálọ sínú ihò àpáta

20Ní ọjọ́ náà ni àwọn ènìyàn yóò máa sọ

21Wọn yóò sálọ sínú ihò ìsàlẹ̀ àpáta

22Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́,

← Isaiah 1 Isaiah Isaiah 3 →

Isaiah 2 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002