We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Habakuku 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Habakuku 1 Habakuku Habakuku 3 →

1Èmi yóò dúró lórí ibusọ́ mi láti máa wòye,

2Nígbà náà ni Olúwa dáhùn pé,

3Nítorí ìṣípayá náà jẹ́ tí ìgbà kan tí a múra sílẹ̀ dè;

4“Kíyèsi, ọkàn rẹ tí ó gbéga,

5Bẹ́ẹ̀ ni pẹ̀lú, nítorí tí ọtí wáìnì ni ẹ̀tàn,

6“Gbogbo àwọn wọ̀nyí kì yóò máa pa òwe sí i tí wọn yóò sì máa kọ orin òwe sí i wí pé,

7Ǹjẹ́ ẹni ti ó yọ ọ́ lẹ́nu, kí yóò ha dìde ní òjijì?

8Nítorí ìwọ ti kó Orílẹ̀-èdè púpọ̀,

9“Ègbé ni fún ẹni tí ń jẹ èrè ìjẹkújẹ sí ilé rẹ̀,

10Ìwọ ti gbìmọ̀ ìtìjú sí ilé rẹ

11Nítorí tí òkúta yóò kígbe jáde láti inú ògiri wá,

12“Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ẹ̀jẹ̀ kọ́ ìlú,

13Olúwa àwọn ọmọ-ogun kò ha ti ṣètò rẹ̀ pé

14Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo Olúwa,

15“Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ohun mímu fún aládùúgbò rẹ̀,

16Ìtìjú yóò bò ọ́ dípò ògo, ìwọ náà mu pẹ̀lú

17Nítorí ìwà ipá tí ó tí hù sí Lebanoni yóò bò ọ́,

18“Èrè kí ni òrìṣà ni, tí oníṣọ̀nà rẹ̀ fi gbẹ́ ẹ,

19Ègbé ni fún ẹni ti ń sọ fún igi pé, ‘Di alààyè?’

20Ṣùgbọ́n Olúwa wà nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀;

← Habakuku 1 Habakuku Habakuku 3 →

Habakuku 2 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002