We Believe JesusFé, Esperança e Nova Vida

Esekiẹli 7

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · iorubá

← Esekiẹli 6 Esekiẹli Esekiẹli 8 →

1Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá:

2“Ọmọ ènìyàn, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí sí ilé Israẹli:

3Òpin tí dé sí ọ báyìí,

4Ojú mi kò ní i dá ọ sì,

5“Èyí ni Olúwa Olódùmarè wí:

6Òpin ti dé!

7Ìparun ti dé sórí rẹ,

8Mo ṣetán láti tú ìbínú gbígbóná mi lé ọ lórí

9Ojú mi kò ní i dá ọ sí,

10“ ‘Ọjọ́ náà dé!

11Ìwà ipá ti di ọ̀pá ìwà búburú;

12Àkókò náà dé!

13Nítorí pé òǹtajà kì yóò rí gbà padà

14“ ‘Wọ́n ti fọn ìpè ogun,

15Idà wà ní ìta,

16Gbogbo àwọn tí ó bọ́ nínú wọn yóò sálà,

17Gbogbo ọwọ́ yóò rọ,

18Wọn yóò wọ aṣọ ọ̀fọ̀,

19“ ‘Wọn yóò dà fàdákà wọn sí ojú pópó,

20Wọ́n ń ṣe ìgbéraga pẹ̀lú ohun ọ̀ṣọ́ wọn tí ó lẹ́wà,

21Èmi yóò sì fi àwọn nǹkan wọ̀nyí ṣe ìjẹ fún àjèjì

22Èmi yóò gbójú mi kúrò lára wọn,

23“ ‘Rọ ẹ̀wọ̀n irin!

24Èmi yóò mú kí orílẹ̀-èdè ti ó búburú jùlọ

25Nígbà tí ìpayà bá dé,

26Wàhálà lórí wàhálà yóò dé,

27Ọba yóò ṣọ̀fọ̀,

← Esekiẹli 6 Esekiẹli Esekiẹli 8 →

Esekiẹli 7 — iorubá:

Biblica® Open Nkanda wu Moyo, Nguizani Yimona ayi Minkunga 2002